Oja yi kojosese ye! (O kojosese)
Oja yi kojosese ye!(O kojosese)
Oja yi kojosese ye! (O kojosese)
Oja yi kojosese (O kojosese)
O n se mi bi ki n ma gbese (Oja yi kojosese)
Emi de nijo lese (Oja yi kojosese)
Ma je nri nkan ti o je n le gbese (Oja yi kojosese)
To ba gbo marlians ko gbese nile
(Marlians!) (Oja yi kojosese)