Lyrics
idamu o to SI mi
Fi opin si Kai
nidi ise mi ti monyan yii ko yemi
ko ma ye sile fun mi dakun jowo ponmile
a ni idamu o to simi fopin si Kaiiiii!
yaa roobi
iforo o to simi fopin si kai
nidi ise mi ti monyan yii ko yemi
koma ye sile fun mi dakun jowo ponmile
Iran alagbede Fi n Dara ni bosefe